Oro awon Boko Haram ti di egbirin ote, baa se n pakan lokan tun ru. Awon omo iko Boko Haram tun ti pa awon eniyan bi mokandinlaadota. Ni ojo Aje to koja yii ni Ipinle Yobe ati Borno.
Nipa ti Ipinle Yobe, agbegbe kan ti n je Buni Yadi to wa ni ijoba ibile Gujba ni won ti lo fun awon soja ni akamo lojiji ti won si pa awon bi ogun ni ipakupa. Ni agbegbe yii kan naa lagbo wi pe won ti pa oga olopa DPO (Divisional Police Officer) ati awon olopa bi ogun.
Nigba ti awon eniyan bi mesan-an mii fi iku sefaje ni Ipinle Borno lainidi kankan pataki lati owo awon Boko Haram.
"We counted up to 20 dead soldiers
and 20 policemen when the attackers left our village after operating for almost two hours.
"They overpowered the security operatives on duty and also burnt the military base and police station in the town ." Okan lara awon olugbe agbegbe ijoba ibile Gujba to wa ni Yobe.
Home / Iroyin /
Oro To-N-Lo-Lowo
/ Boko Haram Pa Ogoji Eniyan: Won Pa Soja, Won Pa Olopa Ati DPO Ni Yobe
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment