Smiley face

Awon Omo Wewe Bo Yinka Ayefele Bi...

Olayinka Ayefele se bo ti wi. Lojo ayajo odun awon ewe to waye, Yinka Ayefele pe gbogbo omode jo lati dun won ninu. Oba Tungba tun lo asiko naa lati fi aidunnu re han nipa awon omo Chibok ti iko Boko Haram jiko salo.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment