Olori awon omo agbebon ti Niger Delta to tun je ajijangbara, Alh Mujahid Asari Dokubo ti pariwo si eti aye wi pe iro patapata ni wi pe awon omobirin bi igba sonu eleyii ti won ni Boko Haram lo ko won pamo. O ni agbari lasan ni gbogbo e je ati wi pe awon ara ilu ko jasi bo se n lo ni orileede tia Nigeria. Awon atejade okunrin naa ni yii lori Facebook.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment