Smiley face

'Ma Fowo Kan 'Beyen Ijo Ni O Ba Mi Jooo' -Nicki Minaj

Orisiirisii ona ni awon omobirin olorin eleyinjuege  ilu Amerika fi n pawo yato si ise orin kiko. Opolopo won tun maa n ya orisiirisii aworan to le mu omo gbagbe ile lati se fi ipolowo oja.  Okan iru e ni yii ti Niicki Minaj se fun Myx Fusions Moscato.



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment