Olori ijo Triumphant Assembly ti koro oju si bi awon omobirin bi igba (200) se di awati eleyii ti awon Boko Haram ko sabe ti enikeni ko si mo ohun ti won fi won se lowolowo bayii.
Gege bi oro ori ero Twitter ti baba yii fi sita, eleyii to jade loju opo @albertoduwole lo ti n pariwo ba yii wi pe:
"NO MORE STORIES...PLEASEEEEE"
Ojise Olorun Oniwaasu agbaye yii n be awon ijoba ki won ye gbe awon ara ilu mora mo, ati wi pe ki won se ohun to ye lati mu nnkan pada bo sipo pada.
Oro to wa nile yii ti kan omode, bee lo si ti kan agbalagba.
#BringBackOurGirls
0 comments:
Post a Comment