Gege bi oun ti omobirin yii so, o ni won tun ji BlackBerry Z10 eleyii ti owo re to bi $500 (N80K) ti oko afesona re fi ranse si wi pe ko maa fi se 'bisgirls' ni kampoosi. Sugbon igba ti Omidan yii yoo ye eru wo, sokoleeti, nnkan isere omode ati magasiini alaroye lasan lo ba nibe ni oro ba di gobe.
"My fiancé who lives in the USA, sent me a package consisting of a diamond ring, BlackBerry Z10, PS, chocolate bar and magazine. "He could have used DHL, but I told him not to worry that I would get it through NIPOST because it was not my first time of using the service. He sent it in March, this year. "I went to the UNILAG post office last week Monday when I was told the package had finally arrived. But on getting there, I discovered the package had been tampered with and the diamond ring and BlackBerry Z10 were not there."
Awon osise ile ifiwe ranse naa so fun Victoria wi pe ohun ti won fi ranse ni awon fi jise ko si eniboodi to tu eru re wo. Oro yii bi Victoria ninu loba gba Sabo Police Station lo lati lo fi ejo sun awon olopa alaso dudu.
Awon olopa gba egberun marun-un (5K) owo naira ki won to mu kondo tele Victoria lati lo ba wa oruko re ti won ji.
Oko afesona Vitoria, Gbolahan Ijimayowa naa pe lati Dallas ni ilu Amerika lati jeri si oro naa.
"I sent the package on March 11, 2014 through the United States Postal Service.
"I gave my fiancée the tracking number of the package so she could monitor it. I told her to keep checking at the post office, because I knew it could take up to four weeks before it would be delivered. But when the package finally arrived, they didn't inform her.
"It was after two weeks that she was called by the UNILAG branch. I sent her the diamond engagement ring because we are planning our wedding soon. We have already had our introduction and engagement; then the BlackBerry Z10, and the PS, which is for my cousin. But the ring and BB were missing. "This is the way we spoil this country. I am sure the ring and BB were taken in the UNILAG office of NIPOST. They should be quizzed by the authorities. They should not be allowed to go scot-free. We need to have those things back."
Sebi won ni a gbo ejo enikan da, agba osika ni. Awon osise NIPOST naa so tenu won nipa isele yii.
"Victoria indeed came here and made complaint that her package was tampered with and we have set up
our internal investigation team to look into the matter and find out what exactly happened to the package. "The complaint has also been directed to our district in Somolu and they are presently looking at it." Mbah Udonbanga to je osise NIPOST Ohun ti a tun gbo ni wi pe won na Vitoria nigba to n pariwo le won lori ni ofiisi ifiwe ranse naa.
"She said somebody threatened to slap her; did you ask her if she was
slapped eventually? Her attitude was very bad when she came here, but she's a customer and we had to just accommodate her that way."
Awon oniroyin kan si alukoro awon olopa fun Ipinle Eko, Arabirin Ngozi Braide lori egberun marun-un owo naira ti oga poliisi gba sapo lai se kalokalo.
Ohun ti Ngozi so naa ni wi pe awon yoo kan si awon oniroyin later ti awon ba se iwadii oro naa dele daada. Gege bi oro Ngozi, oni 'Nfestigasan-an tesiwaju'
Ohun to ba kaluku, otooto ni. Iya n ronu, omo n roka. Ilu Malaysia ko ti ri Baalu to sonu lojosi, awon omobirin bi igba ti Boko Haram ji ko salo ti di apero fun gbogbo omo Nigeria, awon olopa n wa talo gba egberun marun-un owo naira lowo Victoria, Aunty Vikky ni Blackberry Z10 lo je awon logun ju bayii, ogun bilionu owo dollar ni Sanusi n wa ti won fi ro loye.
Olayemi Oniroyin, iroyin le mi wa kiri ti mi o fi sunle mo. Ohun to ba kaluku, otooto ni.
E ku asiko yii!
0 comments:
Post a Comment