Smiley face

Boko Haram Ti Pada Wa Ji Awon Omobirin Mokanla Mii Ninu Ijamba Tuntun To Waye

Sebi awon omobirin bi igba (200) ti iko Boko Haram jigbe salo ni gbogbo ilu si n pariwo "e ba wa wa awon omobirin wa pada".

Eleyii ti apero naa n lo lori ayelukara pelu oju opo #BringBackOurGrils.

Isele tuntun mii tun waye lojo Aje to koja yii nibi ti iko Boko Haram ti pa awon eniyan bi oodunrun (300) ti won si ko awon omobirin mokanla ti won gbamuse salo ni agbegbe Gamboru ni Ngala to wa ni Ipinle Borno.

Gege akojopo iwadii Olayemi Oniroyin, Gamboru Ngala je ileto kan to paala(to wa laaarin) ilu Nigeria ati Cameroon.

Senato Ahmed Zannah to soju agbegbe naa salaye isele to waye fun ile ise iroyin BBC agbaye.


"The attackers stormed the communities in the night when residents were still sleeping, setting
ablaze houses and shooting residents who tried to escape from the fire.''

"About 300 persons were confirmed
dead after the incident, with several others injured. Almost all the houses in the communities were destroyed by the hoodlums who threw IEDs at the buildings.

"My brother who was at the scene of the attack told me that the actual number of the dead cannot be ascertained but at least they are up to
300.

In fact, as he spoke he wept following the high number of the dead bodies which littered the market."

Okunrin yii tun fi kun un wi pe isele yii sele nikete ti awon osise alaabo (soja) ti won n so agbegbe naa kuro lo si enu bode Nigeria lo si Chad.


"It was just an hour after their withdrawal that the terrorists invaded the town, shooting everyone at sight and setting buildings on fire.

So far 200 vehicles and thousands of houses, shops and an outfit of the Nigerian Customs Service, (NCS) were all burnt".
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment