Oba Rilwan Akiolu olowo Eko ti fi onte lu eni ti yoo gba ipo gomina tuntun leyin ti ijoba Fasola ba kogba wole.
Nje tani eni naa ti Oba Akiolu kan irawo mo lapa?
Eni naa ni Ogbeni Akinwunmi Abode.
Isele yii lo waye lana nibi ifilole iwe itan ara eni (Biography) eleyii ti Ogbeni Abode filole ti won pe akole re ni 'The Art of Selfless Service'.
"We say we are here to launch a
book but we know why we are here.
We the elders had met and discussed and the people have said that
Ambode will be the governor.
"Let no one misquote me, the others (aspirants) have a right to run.
Ambode, may you lead all of them.
Ambode is not Ilaje, he is from Epe and a true Lagosian."
Ogbeni Abode ti sise nigba kan ri gege bi akapo agba ipinle Eko eleyii ti Oba alaye se apeere re gege bi omolubi to fakoyo ju lo.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment