Oni ojo Eti (16/5/14) ni Aare Goodluck Jonathan pinnu lati se abewo si Ipinle Borno lati lo petu si awon eniyan ti Boko Haram ji won lomo ko eleyii ti enikeni ko le so ibi tan wa bayii.
Awon osise alaabo Aare ti wo Ipinle Borno lati ana fun imurasile igbalejo Aare Jonathan. Sugbon si iyalenu awon eniyan, Aare ni irin ajo oun si Ipinle Borno ko ni le 'posibu' mo nitori mojamose laa mo akikanju logun. Akinkanju to ba moja ti ko mosa ni Boko Haram n fi bombu fo lori danu.
Won ni fun awon idi kan to ni i se pelu aabo Aare, abewo naa di ohun ti won wogi le.
Se ki i se wi pe oko Patience n beru akara ado iku Boko Haram?
Oga ooo!
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
I love your blog. Lets go all out for the Yoruba language. Oodua a gbe wa!
ReplyDelete