Smiley face

Ado Oloro Onibeji To Dun Lonii Loja Gikomba Ti Pa Aimoye Eniyan


Adoro oloro onibeji kan lagbo wi pe o dun loja Gikomba to wa ni ilu Nairobi to je olu ilu Kenya lonii. Awon eniyan bi mewaa ni iroyin so fun wa wi pe won ku loju ese nigba ti aimoye awon eniyan farapa.


"The first explosion took place in a minibus and the second detonated in the large Gikomba market." Alaye lati ile ise to n jigiri si ijamba ti ilu Kenya.


"Very many people are injured. I don't know how many are dead but for sure there are fatalities," Mwangi Maina, onisowo ni oja Gikomba.


Aare ilu Kenya, Uhuru Kenyatta ti jade soro lori isele yii. E gbo ohun ti won so.

"Many countries are faced with this particular problem (terrorism). All of us must be united to ensure that we fight it."

"We will do what we can as a government. We in Kenya, are committed to this fight and we urge Kenyans to work with us."
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment