Smiley face

Iro Ni Won Pa Mo Oga Mi Goodluck Jonathan" Reuben Abati Ti Pariwo Soke




Agbenuso fun Aare Nigeria nipa Eto Iroyin, Ogbeni Reuben Abati ti soro wi pe iro ni won pa wi pe Goodluck Jonathan se ileri lati lo si Ipinle Borno lonii nibi Boko Haram ti ji awon omobirin bi igba ko salo.

Goodluck Jonathan wa ninu baalu bayii, ilu France ni baba n lo fun ipade pataki ti yoo waye ni Pariisi.

Sugbon sa, o se je akoko yii ni Reuben Abati tako iroyin naa?

Nigba to je wi pe ati bi ojo meta seyin ni awon ile ise iroyin agbaye bi CNN ti n kede wi pe GEJ n mura lo sibi won ti ji won lomo ko salo?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment