Smiley face

Oko Ati Iyawo N Ba Ara Won Sun Ninu Soosi

Awon olopa ti gbe toko-taya ti won n ba ara won sun ni ile ijosin kan to wa ni Salt Lake City, Utah ni ilu Amerika.



Wilson Benally eni odun merindinlogota (56) lo n ba Sandra Kruser aya re, eni ogota odun (60) sun ni koro kan to wa ni ile ijosin Sacred Heart Catholic Church nigba ti eto igbeyawo kan n lo lowo ninu ile ijosin naa.

Igba awon eniyan ka won mobe, igbadun naa ti wo won lara gidigidi to je wi pe won ko tile kobiara rara si awon eniyan ti n wo won.

Won tun so kan won loju wi pe ohun ti won se ko bojumu ni ile Oluwa, sibesibe n se ni won kotiikun ti won si n ba 'isin' ti won lo lonimiliki legbe kan ko to di wi pe awon olopa wa ko won lo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment