Omobirin yii lo so omo re, omo osu kan mo aso igbeyawo lojo ayeye igbeyawo lo ba si bere si ni wo omo naa nile wo inu soosi. Nje kilode to fi wu iru iwa bayii? O ni oun fe ki omo oun kopa ninu eto igbeyawo oun ni.
Awon aye ti bere si ni bu enu ate lu iwa obirin yii eleyii ti won se apere re gege bi odaju. Omobirin naa si ti lo fesi ranse pada lori Facebook re nibi to ti so wi pe' ki lo kan yin nibe, Soboloyoke?'
Iwa ibaje gba a ni arabinrin na hu.
ReplyDelete