Smiley face

Wahala Awon Omo Poli Ati Olopa Ni Yaba

Ifehonuhan awon omo Poli ni Yaba to wa ni ilu Eko pada lagbara koja ohun ti awon olopa le daduro. Ohun to koko sele saaju ni bi awon olopa se gba maalu ti awon omo akekoo ra lati paje lojo ayajo ijoba awa-ara-wa. Pipaje maalu yii ni awon omo akekoo yii fi n se apere iwa apapin ti n lo ninu ise-ijoba Naijeria. Leyin opolopo wahala, won pada gba maalu naa pada eleyii ti won tun fi bere ifehonu won lakotun .


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment