Smiley face

Awon Oba Alaye Marun-un To Lowo Ju Ni Ile Afirika

Iwe iroyin magasiini Forbes ti ile Adulawo ti se atejade awon oba alade marun-un to lowo ju ni ile Afirika, meji ninu won je omo Nigeria.


1. King Mohammed VI, Morocco
Apapo owo re: $2 billion 
Orisu owo re: Okoowo
2. Oba Obateru Akinrutan, Ugbo Land, Nigeria
Apapo owo re: $300 million
Orisun owo re: Epo Robi (Oil)
3. Oba Okunade Sijuwade, Ile-Ife, Nigeria
Apapo  owo re: $75 million 
Orisun owo re: Ise agbase, dukia ile ati epo robi

4. King Mswati III, Swaziland
Apapo owo re: At least $50 million
Orisun owo re: Okoowo (Investments) 

 
5. Otumfuo Osei Tutu II, Ashanti, Ghana
Apapo owo re: $10 million
Orisun owo re: Dukia ati Goolu
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment