Omobirin ti awon omo ita kan fi tipatipa ba sun ni osu kinni odun 2014 ni agbegbe Bariga to wa ni ilu Eko nigba to n ji lo ibi ise re ni nnkan bi ago marun-un abo idaji ti salaye iriri re fun awon oniroyin. Omobirin naa salaye wi pe ayewo ti oun se nikete ti isele naa sele ti fidi re mule wi pe oun ti ni kokoro arun kogboogun ti won pe ni HIV.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment