Smiley face

Oba Oge Rin Ihoho Wonu Oja

Ayeye ifi-ami-eye-danilola eleyii ti agbarijopo awon ile ise alaso oge ilu Amerika se agbekale re ti won pe ni Annual Council of Fashion Designers of America Awards waye lana ojo Aje. Nibi yii ni won ti fi ami eye Oba Oge da Rihanna lola. Rihhanna si jewo ara re gege bi oba oge pelu aso ti n mu awon eniyan dato lenu, awon eniyan yanu kale bi igo taada won ko sile panu de mo nigba ti won ri iyanu nla to ju iyanu lo. 

E jowo, igba wo ni Jesu so wi pe oun pada bo na?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

3 comments:

  1. Adura mi ni wipe, ki Olorun ba omobirin naa pade ki oto pe ju.

    ReplyDelete
  2. emmanuel abiodun3 June 2014 at 10:37

    Amin oo. I decree dat d power of unclean spirit b broken in her life n d chain of d devil upon her heart be losend to d glory of God in d name of Jesus Christ.

    ReplyDelete