Smiley face

Awon Omo Egbe Okunkun Fi Eje Omoge Se Etutu Ni Ilu China

Awon omo egbe okunkun kan ti won je 'All-powerful spirit', ti oruko mi ti won je tun ni 'Quannengshen' ti seku pa odomodebirin ti ojo ori re ko ju nnkan bi ogun odun lo (20) ni ile ounje igbalode McDonald to wa ni ilaa-oorun ilu China. 
Ohun ti a gbo ni wi pe okan ninu awon omo egbe okunkun mefa ti won pa beere  nomba foonu omoge naa eleyii ti omoge naa ko lati fun won. 
Awon kan ti isele  naa soju won salaye wi pe won fe mu omo naa wo inu egbe won ni eleyii to ko lati gba 'waasu ihinrere' ti won n so si i leti ki oro to di wahala nla. 
Ohun to je kayeefi fun gbogbo eniyan ni wi pe bi omoge yii se n pariwo nigba ti won fo irin mo lori, ko si enikeni to le duro gbaa sile lowo awon eniyan ika naa titi emi fi jade lara re.
  Nibayii, awon olopa ti ko awon onise ibi naa pamo sinu ogba ewon lati fi won jofin. 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments: