Smiley face

E Wa Wo Eru Nla Leti Odo Miami

Idunnu nla lo je fun toko-taya ti won se ayeye igbeyawo won leti odo Miami ni ilu Amerika nigba ti won foju kan Ogbontari Akoni Obirin elere idaraya Long Tennis leti odo nibi to ti n se faaji pelu awon ore re. Sebi eni ba ba onire yo dandan ni ko ri ire.Eyi lo mu Serena Williams dide mo won lati ba toko-taya naa ya foto.
 
Bi Cristiano Ronaldo se gbe irawo agbaboolu to dara ju lagbaye dani ti a ba n so nipa ere boolu alafesegba bee gege ni Serena Williams naa gbe irawo elere idaraya to daraju lagbaye labala ti awon obirin dani ninu ere Long Tennis.
 Eyin naa e wo eru kabati. lol

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment