Awon Yoruba ni tori omo la se n sise, o le je oro yii ni Floyd Mayweather Jr ranti to fi ko $50,000 (N8M) sile fun omobirin olorin olokiki ilu Amerika, Nicki Minaj lati wa je iresi nibi ayeye ojo ibi omo re, Iyanna Mayweather to pe omo odun merinla (14). Nicki Minaj ko wa sibi ayeye naa wa korin bee si ni kosi jo, o kan wa ye omo naa si lasan ni. Nicki Minaj ko lo ju wakati kan lo nibi ayeye yii to fi pada sile.
Leyin wakati kan ni N8,000,000 million ba jo tan raurauGbogbo akoko ti Nicki lo nibi ayeye naa foto lo fi n ya pelu omo olojo ibi
#Bujebudanu
0 comments:
Post a Comment