Smiley face

Iru Ife Wo Leyii?


Nje a le pe iru ife eyi ni ife otito? A bi ka so wi pe o nidi kan pataki ti bobo yii fi lo fe arugbo oyinbo.

Eniwee, won n ja lorun ko kanye. Koko jabele... Ohun ti elomii n se nikoro yara re ju eleyii lo.

Sugbon sa, se bobo yii naa ni yoo maa ku awon mummy mole bi aso oke? Nnkan ti mo mean ni wi pe se oun naa ni yoo ma kerewa granma?
Wahala wa o! LOL

posted from Bloggeroid

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment