
Omo Baba Olowo, Davido ti darapo mo awon irawo olorin lagbaye nibi ami eye BET ti yoo waye ni Los Angeles lonii ojo Aiku [29-6-14 ]. O ti to bi ojo meta bayii ti David Adeleke ti wo ilu Amerika nibi to ti n pate orin kiri igboro ti gbogbo awon ololufe re si n ba naja re witiwiti.
Ninu iroyin mi, Ibrahim Ayodeji omo Balogun(Wizkid) eni ti a bi ni ojo kerindinlogun osu keje odun 1990 naa wa ni ilu New York bayii. O si seese ki oun naa gbe ori wole sibi amin eye BET olokiki naa.







posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment