Smiley face

Keshi Ti Kede Eye Asa Metalelogun Ti Won Yoo Jagun Ni Ilu Brazil

Olori gbe agbaboolu Super Eagles ti Nigeria, Olukoni Stephen Keshi ti kede awon omo egbe Super Eagles ti won yoo kopa lati soju ile Nigeria ninu idije boolu agbaye ti yoo bere ninu osu yii ni ilu Brazil. Awon akoni naa ni yii:

Goalkeepers: Vincent Enyeama, Austin Ejide, Chigozie Agbim


Defenders: Joseph Yobo, Elderson Echiejile, Juwon Oshaniwa, Godfrey Oboabona, Azubuike Egwuekwe, Kenneth Omeruo, Efe Ambrose, Kunle Odunlami


Midfielders: John Mikel Obi, Ogenyi Onazi, Ramon Azeez, Michael Uchebo, Reuben Gabriel
Forwards: Osaze Odemwingie, Ahmed Musa, Shola Ameobi, Emmanuel Emenike, Babatunde Michael, Victor Moses, Uche Nwofor.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment