Lojo Aiku to koja yii ni awon omo Boko Haram tun sina ibon bole fun awon omo leyin Jesu kan nibi won ti n josin lowo ni ile Oluwa to wa ni Attagara ni Ijoba Ibile Gwoza. Isele yii lo tun waye leyin ojo keta ti won pa Oba Ilu Gwoza, Alhaji Idrissa Timta.
Sugbon o dabi eni wi pe oro naa ti su awon eniyan agbegbe naa pelu bi won se yiju pada si iko omo ogun Boko Haram, ti gbogbo re si di 'faya fo faya' laarin Boko Haram ati awon odo ilu.
Ija nla sele laarin awon eniyan Gwoza ati Boko Haram lojo isimi, gongo so ni Ipinle Borno.
Awon omo ogun Boko Haram bi metadinlogoji (37) ni won mu bale lojiji. Iroyin ti a gbo ni wi pe awon eniyan naa ti n mura won sile tele eleyii to ba awon omo ogun Boko Haram gan-an lojiji.
Olori awon omo leyin Jesu ti Ipinle naa, Rev. Titus Pona ti jeri si isele yii.
“I was told by my members that 37 suspected Boko Haram members were killed after an attack on Attangara and Agapalwa villages .
“Most of the villages attacked in Gwoza , Bayan Dutse area since a week ago have over 80 per cent Christian population.”
Okunrin kan ti n je Adamu ti isele naa soju re salaye wi pe awon mu awon meta ninu awon omo Boko Haram naa laaye. Alaye okunrin naa ni yii:
'Our church has some men who provide security, especially when service is going on. As we were holding our service on Sunday, we started hearing gunshots and everybody fled. Some jumped through the windows and ran into the bushes. Some who live close to the church managed to run to their homes.
“Men in the community however mobilised immediately and pursued the Boko Haram men.
“They came with motorcycles and a car but our people killed many of them and arrested three.
“I later learnt that nine people in the church were shot dead’’.
Home / Iroyin /
Oro To-N-Lo-Lowo
/ Ija Nla Laaarin Boko Haram Ati Awon Ara Ilu Waye Lojo Sunday To Koja
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment