
Awon osere tiata dabi gègé ikowe lowo awon adari fiimu sinima agbelewo. Ara to ba wu won ni won fi awon osere da. Eniyan ti ko le ̣pa adiye lasan le denu sinima ko di ogbologbo apaayan odaju tabi ika adaniloro. Sebi ise ti won ni.
Ibi ise aje ni Iyabo Ojo wa losan oni. Oju re ko si rerin rara. Godmother awon omo aye o ni gba noosensi lowo eniboodi. Fiimu tuntun ti won ya lowo ni.
E ku oju lona!


Ninu iroyin mi fun awon omoge asiko nikan soso. Aso oge tuntun yii ni mo ni ki n fi han yin. Gege bi alaye awon onise oge, won ni e le wo aso yii lo si pati ojo ibi tabi awon ode mii to fara pe. Sugbon ko si alaye boya ilepa ati orobo le wo orisii aso oge yii. Sugbon gege bi akiyesi mi. Aso yii maa daa fun ilepa tabi semi-orobo (lol) ni kan.
Eniwee, won ko ni ki n suusi fun yin o; won ni ki n fi han yin ni.

posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment