Lori oro yodiyodi to je orisii eroja omolangidi kan ti awon obirin maa n ti bodi lati fi dipo ojuse okunrin si obirin, eleyii ti Bisi Ibidapo ko wole lati oke okun fun tita ti pade di gobe nla bayii laarin osere naa ati ara ilu.
Opolopo awon ololufe Bisi Ibidapo lo je wi pe inu won ko dun si bi oserebirin naa se lo ko orisii eroja naa wole. Ati igba ti Bisi si ti ko omolangidi naa wole lo ti je wi pe awon esi to n gba lenu awon omo Naija ko dara rara.
Opolopo awon eniyan ri eroja naa gege bi irinse esu eleyii ti ko bojumu ni awujo wa rara.
Oro yii bi Bisi ninu, o si ti foro ranse pada si awon onitukutu nigba to foro wero pelu awon akoroyin iwe iroyin SUN ti ile Nigeria.
"I did not open a sex toyshop. I sell
men and women under wears and a
few other things.
I also have a section for body massage, body polish and other things that are related to that. On the issue of sex toys, I have this to say, if I sell sex toys so what?
Nigerians are a bunch of hypocrites. They make issues out of non-issues. When I travelled to London I saw some newly wedded couples buying sex toys but back here, Nigerians believe that those that buy sex toys are harlots.
In fact, there is dignity in the use of sex toys. I am not into the sales of only sex toys but there is a big market for them."
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment