Orisiirisii la o maa ri lagbo osere. Tuntun ti mo tun ri ni yii lati inu iwe iroyin Vanguard ojoojumo ti ile Nigeria.
Oserebirin Seyi Hunter lo so fun awon oniroyin wi pe odindin ni oun si wa bi ataare ati wi pe oun o se 'kerewa' ri.
Kii se wi pe oniroyin bi ni ibeere to jo mo iru nnkan bayii ni san-ansan, oro kan oro ni omobirin naa fi soro koja lori re.
E je ka gbo bi iforowero naa se lo:
"I'm not looking for a stinkingly rich
man. If he has allthe money without
good attributes, then he's not for me.I
like humble people.
So, he has to be humble, God-fearing, extremely nice, very romantic and loving.Yes.
I was attracted to him(oko afesona re nii soro nipa re) because of the fact that he's born again, spoils me with gifts and puts my needs before his own.'
Oniroyin naa pada bi wi pe ewo lo se pataki si ju ninu owo ati 'adun-ma-deeke'.
"I know nothing about sex, I'm a virgin. Money is more important to me in a relationship."
Awon Yoruba ni eniyan meji kii padanu iro. Ti eni won ba n paro fun ko ba mo, eni i paro lokan ara re yoo mo wi pe iro ni oun un pa.
Ati wi pe ko si idaniloju wi pe iro ni omobirin naa n pa.
Abi eyin ti gbo ise re wo ri ni?
Sodiafo, ko kan'ye..
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment