Smiley face

Won Ti Gbe Ade Oba Orin Ile Afirika Fun Davido Ni Ilu Amerika


Sebi ise orin ni Edua oke fi ran Dafiidi wa sile aye. Awon Yooba si bo won ni ibi gbogbo lo gba alagbara. Lati Afirika lo si ilu Amerika, Davido gbayi, o gbeye pelu amin eye Best African Act ti BET Awards 2014 ti won fi da lola lonii [29-6-14] ni ilu Amerika.






posted from Bloggeroid

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment