
Eyi ni die lara awon aworan Tiwatope Savage nibi amin eye BET to waye ni Los Angeles lana [29-06-14]ni ilu Amerika. Bakan naa, se o gbagbe wi pe mo ni Wizkid naa ti wa mi ilu New York saaju igbayii. Ireti wa si ni wi pe o ye ki ohun naa wa sibi ayeye ami eye naa. Sugbon ko ti si aridaju boya Ibrahim de L.A





Wizkid niyii pelu Wale ni ilu Amerika.

posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment