
Orisiirisii èdè tuntun lo n jẹyọ latari àsà ti àwon ọmọ olórin Fuji ñ da. Sùgbon asa kii se ti awon omo onifuji nikan mọ, awon elere tiata naa ti n seda asa tuntun eleyii ti gbogbo eniyan n jẹ lenu bi obì.
Lara awon osere ti won feran asa dida ni Soji Omobanke. Gege bi ajosepo re pelu Pasuma, awon eniyan gba wi pe boya Pasuma lo n jasi awon asa tuntun naa . Sugbon omokunrin naa ti salaye bi oro se ri gan.

'Baba mi ni Pasuma, olórí oko, Oga nla 1(omokunrin n kawo soke lati juba Pasuma bi o se n daruko Oga Nla1). Se e ri, Edumare to se ti Okoya oun naa ni kò jẹ́ ki awo faya.
Fújì ni Pasuma n kọ, actor le mi, e jọ se n gbadun mí? Se e ti ri kò jọ ara won rara. But Olorun kan naa lo fun onikaluku ni inspiration to n lo ti awon aye den se kini...ti awon aye den tewo gba. Bo se n lo niyen.'
Oniroyin: Awon kan so wi pe boya igbó ti e maa n mu lo maa n jinja swaga yin.
Soji: [omokunrin naa bu serin, o si bere si ni so ede ẹ̀gbá lénu] Hehehehehehe! Baba mi ki laa wi nan? Igbo? Me ti mu siga ri. Isokuso re won so kiri o. Ma da won lohun oo.[ omokunrin naa tun bu serin ko to wa dake awada. Leyin eyi lo pada si soro geere]
Se e ri awa onitiata, orisiirisii ni awon eniyan maa n so nipa wa eleyii ti ko ri bee rara. Se e ri, ti won ba so wi pe 'ma gbẹ́sẹ̀ le ju', tẹ diẹ ko release lo le mu yan pe ni ile aye. Onimoto to gbese le ti ko release ni won pada le obituary won ni oro ile aye jẹ.
Orisiirisii ni awon eniyan maa so nipa e , ti e ni pe ko maa gbese le, iwo kan realease wa ri pe ile aye e maa dun fun e gan-an."
Lara awon asa Soji omo Banke ni 'Buate' eleyii to ti di gbajugbaja.

posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment