Smiley face

SANUSI TI LO WO AWON TI BOKO HARAM DANA SUN NI ILU KAN

Emir  it ilu Kano, Sanusi Lamido Sanusi (eni ti won ti yi oruko re si Malam Muhammad Sanusi II) ti lo se abewo si awon omo ilé iwe to farapa nibi ado oloro to dun ninu ogba ile iwe Kano kan, Kano School of Hygiene nibi ti won ti n gba itoju ni Murtala Mohammed Specialist Hospital lonii ojo isegun.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment