Smiley face

AWON OMO ILE IGBIMO ASOFIN JA BOXING NI IPINLE EDO


Ni ojo Aje to koja yii (23/06/14) ni isele yii sele ni Ipinle Edo nibi ti awon omo ile igbimo asofin bi meta kan ti won ti jawe jokosile fun fe fi tipatipa wole sinu ile igbimo asofin naa.

Nibi won ti n so fun won wi pe ki won ma wole wa ni enikan ninu awon asofin naa to ni skill ti gbe ju blow si okan lara awon oludena, ni oro ba di isu ata yan-anyan-an ni aaro putuputu ojo Aje..y
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment