Smiley face

Davido Fi Milionu Mefa Ra Ago Lasan

Ago tuntun ti Davido omo olorin sese ra ni yii. Gege bi iroyin taa gbo, won ni iye owo orisii ago Rolex yii le die ni milionu mefa nisiro owo Naira ile wa.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment