Smiley face

Gomina Ipinle Maidiguri Nigba Kan Ri Ti Pada Sinu Egbe PDP Lati Inu Egbe APC

Sebi ija lode ni orin dowe ti Senato Ali Modu Seriff to ti fi igba kan je gomina Ipinle Maiduguri fun igba meji labe egbe oselu PDP ko to di wi pe o sawo inu egbe APC. Nibayii, agba oloselu naa ti pinnu lati pada sinu egbe PDP to je ese aaro re.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment