Awon egbe Man O' War ile Nigeria ti bu ola fun Muyiwa
Ademola ati Femi Adebayo fun ipa ribiribi ti won ko lawujo wa. Awon agba
osere naa ko sai padan loju gbogbo awon eniyan lati fi idunnu won han
si aponle ti won fi ye won si.
Ti e ba wo oju Muyiwa daada, e ri wi pe o dabi eni to ti setan lati wo inu igbo Sambisa lati lo ko awon omo Chibok jade wa. Errk
0 comments:
Post a Comment