Smiley face

Awon Omo Ibeji Shola Sobowale Ni Yii

Awon omo ibeji,Taye ati Kehinde Sobowale ni yii ti won je omo bibi inu Shola Sobowale.
Edumare ko da awon omo naa si. Ohun ti a gbo ni wi pe awon omo naa ti fe gbe ise fiimu bayii lati ibi ti iya won ba de. Koda, fiimu won tuntun ko ni pe jade.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment