Smiley face

Ijamba Ina Alagbara Ba Faaji Je Ni Ilu UK


Ina nla jo lonii ni Eastbourne Pier to wa ni East Sussex nibi ti aimoye ori ti n se faaji to nipon bi ponmo ti won ta loja Orita Merin to wa ni ilu Ibadan. Ina yii ba faaji won je, aimoye dukia lo sofo sugbon emi kankan ko ba isele naa lo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment