Mo ri ohun kan ninu foto yii ti ko boju mu gege bi omoluabi, eleyii ti mo gba wi pe opolopo awon eniyan naa ri pelu. Sugbon o ya mi lenu wi pe ko si eniyan kankan to soro ba ohun ti ko bojumu ti mo ri naa.
Bi o tile je wi pe awon eniyan naa o fe otito; sibesibe, o ye ki awon eni to sunmo'ni le toni sona gidi.
Ti enu eniyan ba n run, sasa lore to le so fun ore wi pe enu re run lo fonu. Ore oju laye n se, ore o denu. Won tuto funfun sita , won fi eje pupa sinu.

0 comments:
Post a Comment