Osere onitiata meji, Ini Edo ati Desmond Elliot kawe gboye nipa imo ofin jade lonii ni National Open University of Nigeria.
Ohun ti Ini Edo so ni yii nipa aseyori won.
"I feel like like sm 12 years ago.. @desmondelliot we are doing dis for real.
#openuniversity#lawstudent#
educationisdekeytosuccess#if we can do it,u can do it.nvr too late"
A fi asiko ki won ku ori ore.
0 comments:
Post a Comment