Ninu fidio tuntun to jade, Abubakar Shekau, olori Boko Haram ti je ko ye gbogbo aye wi pe ado oloro to dun ni agbegbe Folawiyo,Apapa ni ilu Eko losu to koja [25-6-14], nibi ti eniyan marun-un ti ku je ise owo Boko Haram. Bakan naa ni eyi to waye ni ilu Abuja lojo kan naa yii nibi ti eniyan mejilelogun ti jona wuruwuru.
'Emi loosa ti n dun labe aso, emi ni irumole to ranse ado iku oloro si ilu Eko.' Shekau lo so bee ninu fidio tuntun to jade
0 comments:
Post a Comment