Agbaoje agbaboolu omo ilu Chile, Alexis Sanchez ti setan lati darapo mo egbe agbaboolu Arsenal lati inu egbe agbaboolu Barcelona to wa.
Titi di akoko iroyin yii, ko ti si atejade kankan eleyii to se afihan iye owo ti won fi ra agbaboolu naa.
Alexis Sanchez naa foju han ninu idije boolu agbaye ti n lo lowo ni ilu Brazil nibi to ti gba ayo meji wole fun ilu re ki won to dari pada wale ni abala keji idi naa.
E le ka ekunrere iroyin to ku nibi: http://www.arsenal.com/news/news-
archive/20140710/alexis-sanchez-agrees-to-join-
arsenal
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment