Smiley face

Osise Ile Ise Redio Ipinle Oyo Gbegbagi

Sebi ko si eni to gbon tan, kosi seni to moo tan. Gbogbo wa la ku die sibi kan. Awon Yoruba sibo, won ni ka dupe lowo eni to ri ni to moju, aimoye ni ko wo ibi taa wa.

Osise BCOS eka ti redio lo gbe ede Yoruba si ara won. Sebi sorosoro ko maa yo oro so ni tori awon to moro o gbo.

Ohun ti Ogbeni Yanju so ni yii:

'E ba mi so fun Lola Osanyin lori eto Eleti-Ofe nileese redio Ipinle Oyo, BCOS laaaro yi pe, won o kii fi ori ikooko soodun.

"Ori okoo (20) ni won fii soodun (300)".

Ni yoo fi je "Okoo le loodun" (320).

Ede Yoruba ko nii baje, bee si ni ko nii parun.' -Yanju Adegboyega ( Igbakeji Olootu Agba fun Alariya Oodua)

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment