Sebi bi a ko ba ku, ise o tan. Balogun egbe agbaboolu Super Eagles,
Joseph Yobo ti gbegbe gbogbo ijakule ti egbe naa koju ni ilu Brazil pelu
bo se fi idunnu ati ayo pade ebi re ni London nibi won ti n gba afefe
tutu sara.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment