Smiley face

Omoge, Mo Je Dodo E Bajebaje' - K1 Fi Ife Han Si Arewa Oserebirin Niwaju Gbogbo Eniyan

Sebi awon Yoruba ni won wi pe omo eni ko ni sedi bebere ka wa fi ileke sidi omo eloomi. Ti omo eni ba daa ka wi, taa ba si ri ileke iyun to daa baa ba ko si nidi ko buru rara. Nibi amin eye ti People City seagbekale re nibi won ti n fi amin eye da awon amuludun lola to waye ni kopekope yii ni K1 oba Fuji ti moriri ise opolo oserebirin, Queen Nwokoye gege bi agbaoje ti n sise takuntakun.

Laaarin opo eniyan ni Baba Yomade ti so oro aponle ati koriya yii jade eleyii to ba oserebirin naa lojiji.

"I love what you are doing, keep doing what you are doing" K1 

Sugbon ohun ti awon oniroyin amuludun ile Naijeria n so bayii ni wi pe ko ma se wi pe ewa obirin naa gan-an lo wu oba Fuji. Nitori won se apejuwe Olu Omo of Lagos gege bi eni to nife orekelewa obirin gidi gan-an. Ore re si dabi igbin tenu mogi o gun un. Won ni ko ni joniloju ti awon ba pada gbo wi pe omobirin naa ti loyun fun Arabambi. Mmmmh!

Nje eyin gba wi pe otito ni akiyesi won?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment