Smiley face

Awon Dokita Ilu China Ba Ise Esu Je Raurau

Ogo ni fun Oluwa! Oke isoroYang Jianbin subu lule lojo ti awon agboje dokita mesan-an (9) pawopo lelori fun odindi wakati merindinlogun (16) lati mu ajaga ati eru aye re kuro. Ilu China ni Yang Jianbin n gbe, ati igba ti o ti wa ni kekere ni ara re ti n so. igba ti o wa lomo odun mejila, won gbiyanju lati ba ge kuro sugbon o tun pada so. Siso naa si n tobi si i titi to fi di omo odun merindinlogoji (37).


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment