Smiley face

Neymar Ti Ko Leta Ranse Si Awon Egbe AgbaBoolu Brazil

Olayemi Oniroyin, gbogbo ede ni mo gbo sugbon eyi ti won so ni ilu Brazil maa n se mi loju baibai.

Neymar, akoni omo agbaboolu ilu Brazil ti ko leta ranse si awon akegbe re lati ori Facebook sugbon ede ilu won lo fi ko eleyii to je ko soro fun mi lati mo pato ohun to ko. Nnkan bi iseju die loku bayii ki ile Brazil koju Jamini ni akoko ti mo n ko iroyin.

Kini oseese ki omokunrin yii ko sinu leta tuntun yii?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment