
Omobirin kan tí wọn se apejuwe re gege bi omo ile Biritiko la gbo wi pe o ba awon okunrin bi merinlelogun [24] ni ajosepo láàrín iseju meji ni ile otin kan to wa ni Calvià ti ilu Spain.
Gege bi alaye ti Olayemi Oniroyin ri ko jọ nipa bi o se rọrùn ki iye awon eniyan wonyii ba omo naa ni ajosepo laaarin iseju meji; n se ni omobirin naa 'yodiskin' seyin bi igba ti obirin tiro to wa gadi seyin bi igba to fẹ́ tọ lori iduro.
Igba ti omobirin yii "chidioke" tan ni awon okunrin merinlelogun yii si bere si ni gba eyin re koja. Bi won se n gba eyin re koja ni won ti ọ̀pá bolu.
Isekuse to waye yii ni awon ti isele naa soju re se apejuwe re gege bi igba ti awon omode n sere pagboyimika bee ni won se yii omobirin naa ka ti won si bee si ni to toonu bi moto taxi ti mbe ni garaji lori omobirin taa wi yii.

Ohun to jo ni loju ni wipe tori igo otin kan ni omobirin naa fi te idi re sile bi afara oyin ti awon eshinshin si bere si ni kun yunmuyunmu lori re. Awon alase ti bere iwadii lori isele naa. Inu awon ara ilu ko si dun rara pelu iru iwa ti won se alaye re gege bi ohun irira ati itiju nla.



Won ti gbe fidio isele naa sita bayii so ori ayelukara
posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment