Ohun kayeefi kan selẹ̀ ni ilu Ogbomosho to wa ni Ipinle Oyo nibi ti Sango Olukoso oko Oya abi-na-loju; a-bina-lenu ti gbe san àrá ńlá pa okùnrin kan. A kò ti le sọ pàtó ohun ti okunrin naa se bayii. Afikun iroyin mbo laipe.

Omobirin kan naa wa ni agbegbe ti ìsẹ̀lẹ̀ yii ti sele nigba ti ara naa san. Sugbon kò kú, mọ̀nàmọ́ná iná àrá nàá kan bo lára ni. Omobirin naa ti wa ni ile iwosan bayii. Awon àgbàlagbà sọ wi pe omobirin naa kan rin si asiko ìsẹ̀lẹ̀ burúkú yii ni ki i se oun gan-an ni Sango fẹ se nijamba.

Maa tun jẹ kẹ e gbọ́ nikete ti mo ba ti gbọ́ wulewule ìsẹ̀lẹ̀ nàá.
Ope lowo Ayo Inawole fun awon aworan yii.

posted from Bloggeroid
E ku ise takun-takun sir, Olorun O ni jeki O reyin loruko Jesu.
ReplyDelete