Awon kan ti n gbe iroyin kan kiri lati igba tojumo ti mo wi pe Alagba Adebayo Faleti ti papoda.
Beeko ni oro naa ri. Alagba Supo Koseemani to je atokun 'Owe Lesin Oro' lori telifisan lo jade laye.
Ki Oluwa ba wa fi orun ke eni to lo.
Alagba Adebayo Faleti si wa lalafia ara.
0 comments:
Post a Comment