Ojogbon Akinwunmi Isola naa ti fidi re mule wi pe iro ni iroyin to wi pe Alagba Adebayo Faleti ti jade laye. O ni n se ni awon eniyan gbe iroyin naa fun ara won.
"Baba Faleti is still very much alive. Many people have called me to inquire about the state of
things with him."He is still very much alive. It is true that he had been indisposed for some time. But he has got better now."The person who has passed on is Alagba Supo Koseemani, the specialist in Yoruba proverbs. I gathered that he passed on in Ibadan on Sunday." Prof. Akinwunmi Isola
0 comments:
Post a Comment